Peteru Keji 3:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ẹ máa dàgbà ninu oore-ọ̀fẹ́ ati ìmọ̀ Oluwa ati olùgbàlà wa, Jesu Kristi. Tirẹ̀ ni ògo nisinsinyii ati títí laelae. Amin.

Peteru Keji 3

Peteru Keji 3:12-18