Orin Solomoni 8:12-14 BIBELI MIMỌ (BM)

12. Èmi ni mo ni ọgbà àjàrà tèmi,ìwọ Solomoni lè ní ẹgbẹrun ìwọ̀n owó fadaka,kí àwọn tí wọn yá ọgbà sì ní igba.

13. Ìwọ tí ò ń gbé inú ọgbà,àwọn ẹlẹgbẹ́ mi ń dẹtí,jẹ́ kí n gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ.

14. Yára wá, olùfẹ́ mi,yára bí egbin, tabi ọ̀dọ́ akọ àgbọ̀nrín,sí orí àwọn òkè turari olóòórùn dídùn.

Orin Solomoni 8