Ìfẹnukonu rẹ dàbí ọtí waini tí ó dára jùlọ,tí ń yọ́ lọ lọ́nà ọ̀fun,tí ń yọ́ lọ láàrin ètè ati eyín.