Orin Solomoni 3:9-10 BIBELI MIMỌ (BM)

9. Igi Lẹbanoni ni Solomoni fi ṣe ìtẹ́ rẹ̀.

10. Ó fi fadaka ṣe àwọn ẹsẹ̀ ìjókòó rẹ̀,ó fi wúrà ṣe ẹ̀yìn rẹ̀,Aṣọ elése-àlùkò tí àwọn ọmọbinrin Jerusalẹmu hun ni ó fi ṣe tìmùtìmù ìjókòó rẹ̀.

Orin Solomoni 3