Orin Dafidi 98:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ẹ kọ orin titun sí OLUWA,nítorí tí ó ti ṣe ohun ìyanu;agbára ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀, ati apá mímọ́ rẹ̀ ni ó fi ṣẹgun.

2. OLUWA ti sọ ìṣẹ́gun rẹ̀ di mímọ̀,ó ti fi ìdáláre rẹ̀ hàn lójú àwọn orílẹ̀-èdè.

Orin Dafidi 98