Orin Dafidi 94:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ jẹ́ kí ó ye yín,ẹ̀yin tí ẹ ya òpè jùlọ láàrin àwọn eniyan!Ẹ̀yin òmùgọ̀, nígbà wo ni ẹ óo gbọ́n?

Orin Dafidi 94

Orin Dafidi 94:3-9