Orin Dafidi 94:21-23 BIBELI MIMỌ (BM)

21. Wọ́n para pọ̀ láti gba ẹ̀mí olódodo;wọ́n sì dá ẹjọ́ ikú fún aláìṣẹ̀.

22. Ṣugbọn OLUWA ti di ibi ìsádi mi,Ọlọrun mi sì ti di àpáta ààbò mi.

23. Yóo san ẹ̀san ẹ̀ṣẹ̀ wọn fún wọn,yóo pa wọ́n run nítorí ìwà ìkà wọn.OLUWA Ọlọrun wa yóo pa wọ́n run.

Orin Dafidi 94