Orin Dafidi 91:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ẹni tí ń gbé abẹ́ ààbò Ọ̀gá Ògo,tí ó wà lábẹ́ òjìji Olodumare,

2. yóo wí fún OLUWA pé,“Ìwọ ni ààbò ati odi mi,Ọlọrun mi, ẹni tí mo gbẹ́kẹ̀lé.”

3. Nítorí yóo yọ ọ́ ninu okùn àwọn pẹyẹpẹyẹati ninu àjàkálẹ̀ àrùn apanirun.

Orin Dafidi 91