Orin Dafidi 88:16-18 BIBELI MIMỌ (BM)

16. Ìrúnú rẹ bò mí mọ́lẹ̀;ẹ̀rù rẹ sì bà mí dójú ikú.

17. Wọ́n yí mi ká tọ̀sán-tòru bí ìṣàn omi ńlá;wọ́n ká mi mọ́ patapata.

18. O ti mú kí ọ̀rẹ́ kòríkòsùn mi ati àwọn alábàárìn mi kọ̀ mí sílẹ̀;òkùnkùn nìkan ni ó yí mi ká níbi gbogbo.

Orin Dafidi 88