Orin Dafidi 87:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Tí mo bá ń ka àwọn ilẹ̀ tí ó mọ rírì mi,n óo dárúkọ Ijipti ati Babiloni,Filistia ati Tire, ati Etiopia.Wọn á máa wí pé, “Ní Jerusalẹmu ni wọ́n ti bí eléyìí.”

Orin Dafidi 87

Orin Dafidi 87:1-7