Orin Dafidi 87:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ní orí òkè mímọ́ ni ìlú tí OLUWA tẹ̀dó wà.

2. OLUWA fẹ́ràn ẹnubodè Sioni ju gbogbo ìlúyòókù lọ ní ilẹ̀ Jakọbu.

3. Ọpọlọpọ nǹkan tó lógo ni a sọ nípa rẹ,ìwọ ìlú Ọlọrun.

Orin Dafidi 87