Orin Dafidi 82:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ọlọrun ti jókòó ní ààyè rẹ̀ ninu ìgbìmọ̀ ọ̀run;ó sì ń ṣe ìdájọ́ láàrin àwọn ẹ̀dá ọ̀run:

2. “Yóo ti pẹ́ tó tí ẹ̀yin óo máa fi aiṣododo ṣe ìdájọ́,tí ẹ óo sì máa ṣe ojuṣaaju fún àwọn eniyan burúkú?

Orin Dafidi 82