Orin Dafidi 79:4 BIBELI MIMỌ (BM)

A ti di ẹni ẹ̀gàn lójú àwọn aládùúgbò wa;àwọn tí ó yí wa ká ń fi wá ṣe yẹ̀yẹ́;wọ́n sì ń fi wá rẹ́rìn-ín.

Orin Dafidi 79

Orin Dafidi 79:1-7