Orin Dafidi 78:70-72 BIBELI MIMỌ (BM)

70. Ó yan Dafidi iranṣẹ rẹ̀;ó sì mú un láti inú agbo ẹran.

71. Ó mú un níbi tí ó ti ń tọ́jú àwọn aguntantí ó lọ́mọ lẹ́yìn,kí ó lè máa tọ́jú àwọn ọmọ Jakọbu, eniyan rẹ̀,àní àwọn ọmọ Israẹli, eniyan ìní rẹ̀.

72. Ó tọ́jú wọn pẹlu òdodo,ó sì tọ́ wọn pẹlu ìmọ̀.

Orin Dafidi 78