Orin Dafidi 78:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n sọ̀rọ̀ ìwọ̀sí sí Ọlọrun, wọ́n ní,“Ṣé Ọlọrun lè gbé oúnjẹ kalẹ̀ fún wa ninu aṣálẹ̀?

Orin Dafidi 78

Orin Dafidi 78:16-25