Orin Dafidi 72:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn tí ń gbé aṣálẹ̀ yóo máa foríbalẹ̀ fún un;àwọn ọ̀tá rẹ̀ yóo sì máa fi ẹnu gbo ilẹ̀ níwájú rẹ̀.

Orin Dafidi 72

Orin Dafidi 72:2-11