Orin Dafidi 72:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun, gbé ìlànà òtítọ́ rẹ lé ọba lọ́wọ́;kọ́ ọmọ ọba ní ọ̀nà òdodo rẹ.

Orin Dafidi 72

Orin Dafidi 72:1-5