Orin Dafidi 66:17-20 BIBELI MIMỌ (BM)

17. Mo ké pè é,mo sì kọrin yìn ín.

18. Bí mo bá gba ẹ̀ṣẹ̀ láyè ní ọkàn mi,OLUWA ìbá tí gbọ́ tèmi.

19. Ṣugbọn nítòótọ́, Ọlọrun ti gbọ́;ó sì ti dáhùn adura mi.

20. Ìyìn ni fún Ọlọrun,nítorí pé kò kọ adura mi;kò sì mú kí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ kúrò lórí mi.

Orin Dafidi 66