Orin Dafidi 66:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Gbogbo ayé, ẹ hó ìhó ayọ̀ sí Ọlọrun.

2. Ẹ kọ orin ògo yin orúkọ rẹ̀;ẹ yìn ín, ẹ fògo fún un!

Orin Dafidi 66