Orin Dafidi 62:11-12 BIBELI MIMỌ (BM)

11. Ọlọrun ti sọ̀rọ̀ níbìkan,mo sì ti gbọ́ ọ bí ìgbà mélòó kan pé,Ọlọrun ló ni agbára;

12. ati pé, tìrẹ, OLUWA ni ìfẹ́ tí kì í yẹ̀.Ò máa san ẹ̀san fún eniyangẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ rẹ̀ bá ti rí.

Orin Dafidi 62