Orin Dafidi 62:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ọlọrun nìkan ni mo fi sùúrù gbẹ́kẹ̀lé;ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni ìgbàlà mi ti wá.

2. Òun nìkan ni àpáta ati olùgbàlà mi,òun ni odi mi, a kì yóo tì mí kúrò.

Orin Dafidi 62