Orin Dafidi 60:10-12 BIBELI MIMỌ (BM)

10. Ọlọrun, o kò ha ti kọ̀ wá sílẹ̀?Ọlọrun, o ò bá àwọn ọmọ ogun wa jáde lọ sójú ogun mọ́.

11. Ràn wá lọ́wọ́, bá wa gbógun ti àwọn ọ̀tá wa,nítorí pé asán ni ìrànlọ́wọ́ eniyan.

12. Pẹlu àtìlẹ́yìn Ọlọrun a óo ṣe akin,nítorí òun ni yóo tẹ àwọn ọ̀tá wa mọ́lẹ̀.

Orin Dafidi 60