Orin Dafidi 60:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ọlọrun, o ti kọ̀ wá sílẹ̀,o ti wó odi wa;o ti bínú, dákun, mú wa bọ̀ sípò.

2. O ti mú kí ilẹ̀ mì tìtì;o ti mú kí ó yanu;dí gbogbo ibi tí ilẹ̀ ti ya, nítorí pé ó ń mì.

Orin Dafidi 60