Orin Dafidi 55:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Tẹ́tí sí adura mi, Ọlọrun,má sì fara pamọ́ nígbà tí mo bá ń bẹ̀bẹ̀.

2. Fetí sí mi, kí o sì dá mi lóhùn;ìṣòro ti borí mi.

Orin Dafidi 55