Orin Dafidi 46:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ọlọrun ni ààbò ati agbára wa,olùrànlọ́wọ́ tí ó wà nítòsí nígbà gbogbo, ní ìgbà ìpọ́njú.

2. Nítorí náà ẹ̀rù kò ní bà wá bí ayé tilẹ̀ ṣídìí,bí àwọn òkè ńlá tilẹ̀ ṣípò pada, tí wọ́n bọ́ sinu òkun;

Orin Dafidi 46