Orin Dafidi 45:16-17 BIBELI MIMỌ (BM)

16. Àwọn ọmọkunrin rẹ ni yóo rọ́pò àwọn baba rẹ;o óo fi wọ́n jọba káàkiri gbogbo ayé.

17. N óo mú kí á máa ki oríkì rẹ láti ìran dé ìran;nítorí náà àwọn eniyan yóo máa yìn ọ́ lae ati laelae.

Orin Dafidi 45