10. Bí ọgbẹ́ aṣekúpanini ẹ̀gàn àwọn ọ̀tá mi rí lára mi,nígbà tí wọn ń bi mí lemọ́lemọ́ pé,“Níbo ni Ọlọrun rẹ wà?”
11. Ìwọ ọkàn mi, kí ló dé tí o fi ń rẹ̀wẹ̀sì?Kí ló dé tí ara rẹ kò fi balẹ̀ ninu mi?Gbẹ́kẹ̀ rẹ lé Ọlọrun; nítorí pé n óo tún yìn ín,olùrànlọ́wọ́ mi ati Ọlọrun mi.