Orin Dafidi 42:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Bí ọkàn àgbọ̀nrín tií máa fà sí odò tí omi rẹ̀ tutù,bẹ́ẹ̀ ni ọkàn mi ń fà sí ọ, Ọlọrun.

2. Òùngbẹ Ọlọrun ń gbẹ ọkàn mi,àní, òùngbẹ Ọlọrun alààyè.Nígbà wo ni n óo lọ, tí n óo tún bá Ọlọrun pàdé?

Orin Dafidi 42