Orin Dafidi 41:2 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA yóo máa ṣọ́ ọ, yóo sì dá a sí.Yóo ní ayọ̀ ní ilẹ̀ náà;OLUWA kò ní fi í lé àwọn ọ̀tá rẹ̀ lọ́wọ́.

Orin Dafidi 41

Orin Dafidi 41:1-10