Orin Dafidi 39:4 BIBELI MIMỌ (BM)

“OLUWA, jẹ́ kí n mọ òpin ayé mi,ati ìwọ̀nba ọjọ́ ayé mi,kí n lè mọ̀ pé ayé mi ń sáré kọjá lọ.”

Orin Dafidi 39

Orin Dafidi 39:1-7