Orin Dafidi 39:12 BIBELI MIMỌ (BM)

“OLUWA, gbọ́ adura mi,tẹ́tí sí igbe mi,má dágunlá sí ẹkún mi,nítorí pé àlejò rẹ, tí ń rékọjá lọ ni mo jẹ́;àjèjì sì ni mí, bíi gbogbo àwọn baba mi.

Orin Dafidi 39

Orin Dafidi 39:7-13