Orin Dafidi 38:1-2 BIBELI MIMỌ (BM) OLUWA, má fi ibinu bá mi wí!Má sì fi ìrúnú jẹ mí níyà! Nítorí pé ọfà rẹ ti wọ̀ mí