Orin Dafidi 37:39-40 BIBELI MIMỌ (BM)

39. Ọ̀dọ̀ OLUWA ni ìgbàlà àwọn olódodo ti ń wá;òun ni alátìlẹ́yìn wọn ní àkókò ìṣòro.

40. OLUWA a máa ràn wọ́n lọ́wọ́, a sì máa gbà wọ́n;a máa gbà wọ́n sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn eniyan burúkú,a sì máa gbà wọ́n là,nítorí pé òun ni wọ́n sá di.

Orin Dafidi 37