Orin Dafidi 37:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn àwọn oníwà pẹ̀lẹ́ ni yóo jogún ilẹ̀ náà:wọn óo máa gbádùn ara wọn;wọn óo sì ní alaafia lọpọlọpọ.

Orin Dafidi 37

Orin Dafidi 37:4-14