Orin Dafidi 37:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Má gbé ara rẹ lọ́kàn gbóná nítorí àwọn eniyan burúkú;má sì jowú àwọn aṣebi;

2. nítorí pé kíákíá ni wọn yóo gbẹ bí i koríko;wọn óo sì rọ bí ewé.

Orin Dafidi 37