Orin Dafidi 32:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ mi fún ọ;n kò sì fi àìdára mi pamọ́ fún ọ.Mo ní, “Èmi óo jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ mi fún Oluwa,”o sì dáríjì mí.

Orin Dafidi 32

Orin Dafidi 32:1-11