Orin Dafidi 31:23-24 BIBELI MIMỌ (BM)

23. Ẹ fẹ́ràn OLUWA, gbogbo ẹ̀yin olódodo,OLUWA a máa ṣọ́ àwọn olóòótọ́,a sì máa san àlékún ẹ̀san fún àwọn agbéraga.

24. Ẹ múra gírí, kí ẹ sì mọ́kàn le,gbogbo ẹ̀yin tí ẹ gbẹ́kẹ̀lé OLUWA.

Orin Dafidi 31