Orin Dafidi 31:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Má jẹ́ kí ojú tì mí, OLUWA,nítorí ìwọ ni mò ń ké pè.Jẹ́ kí ojú ti àwọn eniyan burúkú;jẹ́ kí ẹnu wọn wọ wòwò títí wọ ibojì.

Orin Dafidi 31

Orin Dafidi 31:9-24