Orin Dafidi 29:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ń mú kí òkè Lẹbanoni ta pọ́núnpọ́nún bí ọmọ mààlúù,ó sì mú kí òkè Sirioni máa fò bí akọ ọmọ mààlúù-igbó.

Orin Dafidi 29

Orin Dafidi 29:1-9