Orin Dafidi 27:9 BIBELI MIMỌ (BM)

má fi ojú pamọ́ fún mi!”Má fi ibinu lé èmi iranṣẹ rẹ kúrò,ìwọ tí o ti ń ràn mí lọ́wọ́,má ta mí nù, má sì ṣá mi tì,Ọlọrun ìgbàlà mi.

Orin Dafidi 27

Orin Dafidi 27:8-14