Orin Dafidi 20:1-2 BIBELI MIMỌ (BM) OLUWA óo dá ọ lóhùn ní ọjọ́ ìpọ́njú,orúkọ Ọlọrun Jakọbu óo dáàbò bò ọ́. Yóo rán