Orin Dafidi 2:10-12 BIBELI MIMỌ (BM)

10. Nítorí náà, ẹ̀yin ọba, ẹ kọ́gbọ́n;ẹ̀yin onídàájọ́ ayé, ẹ gba ìkìlọ̀.

11. Ẹ fi ìbẹ̀rù sin OLUWA,ẹ yọ̀ pẹlu ìwárìrì.

12. Ẹ júbà ọmọ náà, kí ó má baà bínú,kí ó má baà pa yín run lójijì;nítorí a máa yára bínú.Ayọ̀ ń bẹ fún gbogbo àwọn tí ó wá ààbò lọ sọ́dọ̀ rẹ̀.

Orin Dafidi 2