Orin Dafidi 18:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni ìsàlẹ̀ òkun hàn ketekete,ìpìlẹ̀ ayé sì fojú hàn gbangba nítorí ìbáwí rẹ, OLUWA,ati nítorí agbára èémí ihò imú rẹ.

Orin Dafidi 18

Orin Dafidi 18:14-19