Orin Dafidi 16:10-11 BIBELI MIMỌ (BM)

10. Nítorí o kò ní gbàgbé mi sí ipò òkú,bẹ́ẹ̀ ni o kò ní jẹ́ kí ẹni tí ó fi tọkàntọkàn sìn ọ́ rí ìdíbàjẹ́.

11. O ti fi ọ̀nà ìyè hàn mí;ayọ̀ kíkún ń bẹ ní iwájú rẹ,ìgbádùn àìlópin sì ń bẹ ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ.

Orin Dafidi 16