Orin Dafidi 15:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. OLUWA, ta ni ó lè máa gbé inú àgọ́ rẹ?Ta ni ó lè máa gbé orí òkè mímọ́ rẹ?

2. Ẹni tí ń rìn déédéé, tí ń ṣe òdodo;tí sì ń fi tọkàntọkàn sọ òtítọ́.

Orin Dafidi 15