Orin Dafidi 145:14 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA gbé gbogbo àwọn tí ń ṣubú lọ dìde,ó sì gbé gbogbo àwọn tí a tẹrí wọn ba nàró.

Orin Dafidi 145

Orin Dafidi 145:4-17