Orin Dafidi 141:9-10 BIBELI MIMỌ (BM)

9. Pa mí mọ́ ninu ewu tàkúté,ati ti okùn tí àwọn aṣebi dẹ sílẹ̀ dè mí.

10. Jẹ́ kí àwọn eniyan burúkú ṣubú sinu àwọ̀n ara wọn,kí èmi sì lọ láìfarapa.

Orin Dafidi 141