Orin Dafidi 140:8 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA, má jẹ́ kí ọwọ́ àwọn eniyan burúkú tẹ ohun tí wọn ń wá;má jẹ́ kí èrò ọkàn wọn ṣẹ.

Orin Dafidi 140

Orin Dafidi 140:1-13