Orin Dafidi 139:22-24 BIBELI MIMỌ (BM)

22. Mo kórìíra wọn dé òpin;ọ̀tá ni mo kà wọ́n kún.

23. Wádìí mi, Ọlọrun, kí o mọ ọkàn mi;yẹ̀ mí wò, kí o sì mọ èrò ọkàn mi.

24. Wò ó bí ọ̀nà ibi kan bá wà tí mò ń tọ̀,kí o sì tọ́ mi sí ọ̀nà ayérayé.

Orin Dafidi 139