Orin Dafidi 136:24-26 BIBELI MIMỌ (BM)

24. ó sì gbà wá lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá wa,nítorí pé ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae.

25. Ẹni tí ó pèsè oúnjẹ fún gbogbo ẹ̀dá alààyè,nítorí pé ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae.

26. Ẹ dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọrun ọ̀run,nítorí pé ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae.

Orin Dafidi 136